Akole ise: onka Yoruba (300-500)

Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta

Figo
300 Oodunrun
305 Oodunrun ole-marun-un
310 Oodunrun ole-mewa
315 Okooleloodunrun odunarun-un
320 Okooleloodunrun
325 Okooleloodunrun ole-marun-un
330 Okooleloodunrun ole-mewaa
335 Ojileloodunrun odin marun-un
345 Ojileloodunrun ole-marun-un
350 Ojileloodunrin ole-mewaa
360  Otaleloodunrin
365  Otaleloodunrun ole-marun-un
370 Otaleloodunrun ole-mewaa
375 Orinleloodunrun odin- marun-un
380 Orinle looduunrun
385 Orunleloodunrun ole-marun-un
390 Orunleloodunrun ole-mewaa
395 Irinwo odin- marun-un
400 Irinwo
405 Irinwo ole- marun-un
410 Irinwo ole-mewaa
415 Okoolenirinwo odin- marun-un
420 Okoolenirinwo
425 Okoolenirinwo ole marun-un
430 Okooleni rinwo ole-mewaa
435 Ojilenirinwo odiin marun-un
440 Ojilenirinwo
445 Ojilenirinwo ole-marun-un
450 Ojilenirinwo ole-mewaa
455 Otaleiriinwo odin marun-un
460 Otalenirinwo
465 Otalenirinwo ole-marun-un
470 Orinlenirinwo odin-mewaa
475 Orinlenirinwo odin-marun-un
480 Orinlenirinwo
485 Orinlenirinwo ole-marun-un
490 Edagbeta odin-marun-un
500 Eedegbeta

 

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: Sise Itoju Oyun Ni Ona Abinibi Ati Ode-Oni

Ipo alailegbe ni Yoruba ka omo bibi si nitori won gbagbo pe lai si omo idile ko le e gboro bee si ni itesiwaju ko le si ni awujo.

 

BI A SE N TOJU ABOYUN NI AYE ATIJO

  1. Dide oyun:- itoju aboyun bere ni kete ti won ba ti fi ye si pe oyun naa ti duro . oko tabi agba obinrin ile yoo mu alaboyun lo odo onisegun agbebi tabi babalawo, onisegun agbebi yii yoo de oyun naa ki o maa ba wale tabi baje titi di akoko ti yoo fi bi omo naa
  2. Sise orisi aseje fun alaboyun:- awon aseje yii lo maa n dena aisan bii, oyi oju, ori fifo, inu rirun, ooru inu abbl ti yoo si mu ki omo naa maa dagba ninu ki o si le gbo daradara
  • Wiwe ati mimu awon egbo igi: eyi yoo fun aboyun ati omo inu re lokun .

 

 

BI A SE N TOJU ABOYUN (ODE-ONI)

NI ode-ni, ni kete ti obinrin ko ba ri nnkan osu re ni yoo ti gba ile iwosan lo lati mo boya oyun ti duro.   Oniruru idanlekoo ni awon eleto ilara nse fun awon aboyun lara idanlekoo naa ni yi:

  1. Lilo si ile- iwosan fun ayewo to peye
  2. Gbigba abere ajesara lati le daabobo omo inu
  • Jije awon ouje asaraloore bii, ewa eje, eran, wara abbl
  1. Mimu omi daradara
  2. Jije eso ati ewebe
  3. Sise ere idaraya ni asiko ti o wo
  • Sise imototo ara atin ayika

 

EKA ISE: LOTIRESO

AKOLE ISE: KEKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN.

Igbelewon:

  • Ka onka lati 300-500
  • Salaye bi a se n se itoju alaboyun laye atijo ati lode-oni

Ise asetilewa: ise sise inu iwe ilewo Yoruba Akayege

 

See also

Onka Yoruba (101 – 300)

LITIRESO ALOHUN TO JE MO AYEYE

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA

Kika Iwe Apileko Oloro Geere Ti Ijoba Yan

EYA GBOLOHUN

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *