AKOLE ISE: BI ASA SE JEYO NINU EDE YORUBA

Asa jeyo ninu Ede Yoruba ninu ipede bii owe, akanlo-ede, ewi ,ise sise abbl.

Apeere

                 OWE ASA TI O JEYO EKO TI AWON ASA YII KO WA
1 N o le waa ku ko le ri oye ile baba re je  

Oye jije

A gbodo ni igboya
2 Faari aseju oko olowo ni mu ni lo Oge sise Ki a maa se koja agbara wa, ki a maa ba te
3 Aroba sa kii Sojo Eru jeje ni awon oba alaye (oye jije) Ki a maa bu ola fun awon alase
4 Obe ti bale ile kii je iyaale ile kii see Igbeyawo Agbodo maa gbe igbe aye alaaafia pelu eni ti ajo n gbe, a ko gbodo se ohun ti enikeji ko fe
Apeere akanlo-ede
5 Baba ti sun Asa Isinku Baba ti ku
6 O ta teru ni pa a Asa Isinku O ti  ku                abbl.

 

See also

ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50)

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN

AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ASEYE

AKOLE ISE: Akoto ode-oni

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *