AFIWE ASA ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ODE – ONI

Awon Yoruba gbagbe pe bi eniyan ba ku yoo lo si orun, yala orun rere tabi orun ti o ni iya ninu won gba pe bi eniyan ba ku, o tun le padawa ya lodo o mo re nipa bibi ige ge bi o mo.

Orisii oku meji ni o wa gege bi ojo ori eni ti o saisi bat i n, awon nii:

  1. OKU OFO: eyi ti o tumo sip e iku omode (iku aitojo). Eni tiko dagba, yala nipa ijamba tabi aisan. Eyi je iku ibanuje laa rin awon Yoruba.
  2. OKU EKO: iru iku bayii niti awon agbalagba ti o ti darugbo kujekuje ti won re iwale asa, awon eni ti won ti gbe ile – aye as ohunribiribi ki won to ku.

Afiwe asa isinke abinibi yato ge de rig be si eto isinku aye ode – oni nitori eto eru igba lode ti oti sun siwaju ju ti a te wala. Ni aye atijo iko si ona abayo si bi a ti se le toju oku ju ojo meta lo, sugbon ni aye ode oni. O seese ki a toju oku si inu iyara tabi ile igboku si ju osu mefa tabi ju bee lo lai dibaje.

Bakan naa, ilana itufo ti yaato sit i aye atijo. Orisirisi awonero igbalode ni o wa ti ale lo lati so eyi di mimo fun gbogbo agbaye.

IGBESE ISINKU

  1. Itufo
  2. Ile oku gbigb (awon ana oku ni o maa n sa ba se eyi)
  3. Oku wiwe (fifa irun oku, ri ree ekannaa)
  4. Oku tite (wiwo aso funfun fun oku pelu lilo lofinda oloo run didun)
  5. Oku sinsin
  6. Alejo sise
  7. Opo sise
  8. Opo sisu

 

See also

AKORI EKO

AKORI EKO: ORO – ISE

YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK

Study in the US, Canada, UK, Germany For Free