AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN

AWON LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN KAN TABI OMIIRAN NI ILE YORUBA NI WONYI,

i               Oya – pipe

ii              Esu – pipe

iii             Orin – arungba

iv             Ijala -sisun

v              Sango – pipe

vi             Iyere

vii            Ese – Ifa

 

ESA – IFA / ORUNMILA:

  • Awon olusi re ni babalowo ati awon aloye ifa .
  • Akoko odun ifa tabi ni gba ti nnkan ba ru awon olusin re loju ni won n pe e.

Ounje ifa

Adie

Ewure

Eyele

Igbin

Eja

Epo abbl

 

Eewo ifa/Orunmila

  • Jije isu titun saaju odun

igbagbo Yoruba ti o suyo ni

  • Ayanmo
  • Ebo-riru ati Olodumare.

IJALA:

  • O je Orisa Ogun
  • Awon Ode, agbe, alagbede ati awon onise irin gbogbo ni olusi ogun.
  • Akoko odun ogun ni won maa n sun ijala.

Ounje Ogun.

Aja

Iyan

Obi

Emu

Esun-isu

Akukodie

 

Eewo Ogun

  • Gbigbe ofifo agbe duro

 igbagbo Yoruba ti o suyo

igi, aranko, eye.

  • Won maa n sun ijala lati fi juba ogun ati lati fi wa oju rere re

SANGO PIPE:

  • orisa yii je olufiran
  • Awon adosun sango ati oloye re ni olusin re
  • Asiko odun sango ni won maa n pe e
  • ilu bata ni ilu sango

Ounje Sango.

Orogbo, agbo funfun

Eewo Sango

Siga mimu, Obi, Ewa sese abbl.

Akiyesi: Sango ni o ni ara ati monamona.

ORIN ARUNGBE:

  • Awon Oloro ni olu sin re.
  • Asiko odun oro ni a n ko orin yii

Ounje oro

Emu

Aja

Eewo Oro

  • Obinrin ko gbodo ri oro
  • a kii ri ajeku oro

orisa yii je orisa atunluuse

igbelewon :

  • Ko iwulo ede Yoruba marun un
  • Ko oro atijo marun un ki o si ko akoto irufe oro bee
  • Ko litireso ajemo esin marun-un ki o si salaye

Ise asetilewa: se ise sise lori akole yii ninu iwe ilewo Yoruba Akayege

 

See also

AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ASEYE

AKOLE ISE: Akoto ode-oni

AKOLE ISE: SILEBU

Ami Ohun lori oro onisilebu meji

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *