Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso
Batani / Ihun Silebu
Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.
Apeere apa silebu ni wonyi;
APA | ALEYE | APEERE ORO | APA |
(a) Odo
Silebu |
Eyi ni ipin ti a maa
n gbo julo ti a ba pa silebu sita. Iro faweli tabi konsonanti aranmupe asesilebu ‘n’ ni won le duro bii odo silebu |
I – le
I – tan
Du-n-du |
‘I’ ati ‘e’
‘I’ ati ‘on’
‘U’, ‘n’ ati ‘u’ |
(b) Apaala | Eyi ni awon iro ti a kii gbo kete kete ti a ba pe oro sita | I – we
I – tan Du-n-du |
‘w’
‘t’ ‘d’ ati ‘d’ |
(c) Abere silebu | Eyi ni iro ti o bere silebu ninu ihun. O le je faweli tabi konsonanti | Kan – ge
I – we I – le |
‘k’ ati ‘g’
‘I’ ati ‘w’ ‘I’ ati ‘I’ |
(d) Apekun silebu | Eyi ni iro faweli ti o pari silebu | Wa
Je Kun |
‘a’
‘e’ ‘un’ abbl. |
EYA IHUN SILEBU
Eya ihun silebu meta ni ede Yoruba ni . Eya ihun naa ni wonyi;
- Ihun eleyo faweli (f)
- Ihun akanpo konsonanti ati faweli (kf)
- Ihun eyo konsonanti aranmupe ase silebu (n)
Faweli airanmupe faweli aranmupe le duro bi silebu kan apeere;
Mo ri i
Mo ra a
Ran – an
Fun – un abbl
Apapo konsonanti ati faweli leje silebu kan soso apeere;
- Ke k – e
- Je j – e
- Fe f – e
- Gba gb – a
- Sun s – un
Eyo konsonanti aranmupe ase silebu le da duro bii silebu apeere;
- Ko m ko – ko – n-ko
- Gbangba – gba – n-gba
- Ogedengbe – o – ge – de – n-gbe
- Gbanjo – gba – n-jo abbl.
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: AWON OWE TI O SUYO NINU ISE ATI ISE YORUBA
Oniruuru owe ni awon agba n lo gege bii oro ijinle ogbon lari pe akiyesi ede si ohun ti o wa ni ayika won tabi lati ronu jinle.
- Owe to je mo iwa ati ise ede eniyan ni woyi;
- Omo ti a fi ise wo ni degba omo ti a fi oju ojo bi ko to gege
- Ogun omode ku sere gba ogun odun
- Eni roar pa eere, yoo rifun re
- Woso de mi ko le dabi oniso, n o se bi iya ko le jo iya to bi ni lomo.
- Owe to je mo ise ni wony i-
ise agba
- Ila kii ga ju onire lo
- A kii gbin alubosa ko hu efo
- Iti ogede ko to ohun a a pon ada si
Ise ode
- Kin ni kan lo ba ajao je, apa re gun ju itan lo
- Kaka ki kiniun se akapo ekun, olukuluku yoo se ode re lotooto ni
- Awodi oke ko mo pe ara ile n wo oun
- Obo n jogede, obo n yundi, obo ko mo pe ohun to dun lo n pa ni
(D) Owe to jemo onsowo tabi owo sise
- Kin ni iya alaso n ta to yo egba dani, abi ewure n je leesi ni
- Ona kan ko wo oja
iii. Eni ti a n ba na oja ni a n wo, a kii wo ariwo oja.
Igbelewon:
- Fun silebu loriki
- Salaye batani silebu inu ede Yoruba
- Ko eya ihun silebu pelu apeere
- Ko owe ti o suyo ninu ise ati ise Yoruba
Ise asetilewa: ko owe ti o je mo meji lara ise abinibi ile Yoruba
See also
AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA
AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE