Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni pe iye ibi ti ohun bat i jeyo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu ti oro naa ni han. Iro meta ni o se pataki ninu ede Yoruba awon ni: iro faweli, iro konsonanti ati iro ohun.
EYA IHUN SILEBU: meta ni eya ihun silebu ede Yoruba. A le fihan nipa lilo ipele koofo: [f], [kf], [N] bi odiwon.
Ipeele kefo
F faweli [ǫ, e, in, an, a, u, o, en]
KF konsonanti [wa, lo, sun, abbl]
N konsonanti aranmupe ase silebu [N] – [n,m].
See also
AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN