Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa julo ni iwon igba ti oro yii ba ti ni ami otooto lori. Ami ori oro meta ni a o gbe yewo ninu iwe yii. Awon naa ni: Ami o oke, ami isale ati ami aarin.
Ami ohun oke ( / ) mi.
Ami ohun isale ( \ ) do.
Ami ohun aarin( – ) re.
AMI OHUN OKE (mi)
ba fe ge gbe
ji ki ni ri
AMI OHUN ISALE (do)
ba fa ge gba
je ka na ra
se si so sun
da de di dun
ya ye yo yin
wa we wo wu
AMI OHUN AARIN (re)
be fe ge gbe
je ki lo re
Gege bi a ti so saaju pe, ami ohun meta ni a o yewo ninu iwe yii. Ki a ranti pe faweli nikan ni a maa n fi ami si lori ati konsonanti aranmupe asesilebu (m/n). Awon wonyi nikan ni won maa n gba ami sori bakan naa ni awon konsonanti yii le da duro gege bi odindi silebu ninu ede Yoruba.
AMI OHUN ONISILEBU MEJI
AMI OKE AMI ISALE AMI AARIN
sibi iji ife
Kunle igba omo
Wale ego ire
Batani kin-in-ni re mi
awo ile ise ipon
ile itun aja apa
aje ede egbe ere
ewe ibi imi odo
ogbo oro oso ose
Batani keji re do
aba ajo ida imo
aje ila ola ife
ere iko ibe amo
are ile iwi ige
Batani keta do mi
egbe ore opa ota
ila otun aba ada
ilu agba Aja ala
ana apa ara amo
Bata kerin do do
ebe ese eje efe
ele ala aja apa
ija ila ifa ika
Batani karun-un do re
ida Dada aga obo
ajo ole obe oje
ope owe.
IGBELEWON
- Ami ohun meloo ni o wa ninu ede Yoruba? (a) meji (b) meta (d) merin (e) marun-un.
- Ami ti o ye lori ‘’ilu’ (ibi ti eniyan n gbe) (a) ilu (b) ilu (d) ilu (e) ilu.
- Ami ti o ye lori ‘’oko’’ (….. ti o je eni oluran lowo iyawo). (a) oko (b) oko (d) oko (e) oko
- ‘’Ogun’’ (a) ipinle (b) je orisa ile Yoruba (d) ohun ti eniyan n mu ti ara eniyan ko ba ya (e) aawo laarin ilu si ilu.
- ‘’obe’’ ni (a) ohun ti a fi je ounje (b) ohun ti a fi n ge nnkan (d) ohun ti o dun ti o larinrin (e) ko ye mi.
ORI ATI ELEDAA
Igbagbo Yoruba ni wi pe Orisa-Nla ni Alamo ti o mo ori. Awon Yoruba gbagbo pe orisa yii ni Olodumare fi dida eniyan le lowo. Oun ni Alamo rere, eni ti o se oju, imu, enu, eti ati eya ara eniyan yooku ni ori. Leyin re ni Olodumare mi emi iye si amo ti Obatala ba mo. idi niyi ti won fi n ki i ni: ‘Ajala Alamo ti mo ori’ tabi ‘Alamo rere’. Ise owo re ni awon eni orisa bi: abuke, amukun-un, aro, afin, afoju ati awon abirun miiran.
IGBELEWON
Salaye lori ori ati eledaa.
IWE ITOKASI:
Adewoyin S.Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S.S.1 Corpromutt Publisher Nig Ltd. o.i 177-178
LITIRESO
KIKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN ( EWI IGBALODE) ‘Taiwo Olunlade. NECO
APAPO IGBELEWON
- Ami ohun meloo ni o wa ninu ede Yoruba? (a) meji (b) meta (d) merin (e) marun-un.
- Ami ti o ye lori ‘’ilu’ (ibi ti eniyan n gbe) (a) ilu (b) ilu (d) ilu (e) ilu.
- Ami ti o ye lori ‘’oko’’ (….. ti o je eni oluran lowo iyawo). (a) oko (b) oko (d) oko (e) oko
- ‘Ogun’ (a) ipinle (b) je orisa ile Yoruba (d) ohun ti eniyan n mu ti ara eniyan ko ba ya (e) aawo laarin ilu si ilu.
- ‘obe’ ni (a) ohun ti a fi je ounje (b) ohun ti a fi n ge nnkan (d) ohun ti o dun ti o larinrin (e) ko ye mi.
- Salaye lori ori ati eledaa.
ISE ASETILEWA
- Iye ami ti o wa ninu ede Yoruba ni (A) meta (B) meri (C) meji (D) okan.
- Fi ami si ori awon oro yii ‘owo hand, Owo town, owo broom’ (A) [w- =w= [w[ (B) =w= =w= [w- (C) [w- [w= owo (D) [w= [w= [w=.
- Ami ti a fa lati isale lo si oke ni ami (A) do (B) re (C) mi (D) faso.
- Orisa ti o mo ori ni (A) esu (B) obatala (C) orunmila (D) Olokun
- ‘Ajala Alamo ti n mo ori’ ni …. (A) Orisa-Nla (B) Esu (C) Olokun (D) Olodumare.
APA KEJI
- Fi ami ohun se iyato laarin awon oro yii: hand, respect, war, medicine, twenty, property, god of thunder ati State in Nigeria.
- Salaye lori Ori ati Eledaa.
See also
Nje e le ba wa se akojọpọ awọn topic kọọkan láti jss1 sí ss3. Èyí yóò wúlò fún àwọn tí wọn ṣẹṣẹ fe bẹrẹ sí ní kó èdè Yorùbá. Mo ni awọn ọmọ ile yibo kan ti won fe máa kọ nipa ede yoruba. Òpó yín yóò wù lo fún wọn láti kọ. Amoran témi niyen o