ORIKI
ORISII
IPA TI WON N KO NI AWUJO
AKOONU
Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won.
Ni aye atijo,iwonba ni ise ti ijoba maa n se fun awon ara ilu.igbega ati idagbasoke ilu tabi igberiko maa n waye pelu iranlowo awon elegbejegbe wonyi, apeere iru egbe bee ni aye atijo ni egbe ogboni.
Apapo awon agba ilu ti won to omo bii Aadota odun ni won maa n wo egbe ogboni. Ojuse egbe ogboni ni lati fun oba ni imoran.Won ni agbara lati da oba lekun tabi le oba kuro lori ite ti o ba si agbara lo.
Ni ode-oni,awon elegbejegbe po jantirere. Apeere won ni :-
Lion’s club
Rotary club
Majeeobaje
Oredegbe ati bee bee lo.
Ni ilu tabi ileto ti awon egbe wonyii ba wa,orisiirisii ise idagbasoke ni won maa n se bii : – tite tabi titun afara se.
- kiko ile ero kaakiri ibudoko.
IWULO ELEGBEJEGBE.
- Awon egbe ogboni maa n kopa ninu eto iselu awon baba-nla wa.
- Won maa n kopa ninu ise bii:- ona yiye,afara odo titun se,aafin oba kiko.
- Won maa n kopa ninu pipese owo ajemonu fun awon akekoo ile-iwe giga,pipese eko ofe fun awon akekoo ile-iwe girama,sisan owo idanwo iwe mewaa.
- Aaro kikojo,owe bibe,eesu kikojo fun iranlowo egbe ati enikookan omo egbe.
IGBELEWON
- Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.
- Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.
LITIRESO
OGBON ITOPINPIN LITIRESO
Akoonu:
Eyi ni awon koko to se pataki ti a gbodo mo nipa iwe litireso ti ijoba ya eyi ti a maa ka. Oun akoko ti a gbodo mo ni oruko iwe, Oruko onkowe, ibudo itan, itan ni soki, awon eda itan, ona isowolo-ede, eko ti a ri ko, asa Yoruba ati beebee lo.
Iwe ti a maa gbe yewo ni OMO TI A TI A FI ISE WO ati ORE MI.
Oruko Onkowe: oruko awon onkowe iwe naa ni: Ojukorola O. ati Aderibigbe M.
Ibudo Itan: n’ toka si ilu ti itan inu iwe yii ti waye, awon ilu ti itan naa ti waye ni:
Itan ni soki:
Awon Eda Itan:
Akanlo Ede Ayaworan: owe, akanlo ede, afiwe, awitunwi, asorege, ifohunpeniyan, iforodara abbl.
IWE AKATILEWA
Simplified Yoruba ati litireso
APAPO IGBELEWON
- a. Kin ni silebu?
- Salaye ihun silebu pelu apeere.
- Pin awon oro yii si silebu
- Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.
- Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.
ATUNYEWO EKO
- Salaye iro konsonanti.
- Salaye iro faweli
ISE ASETILEWA
- ………ni ege oro ti eni lo gba jade leekansoso (a) oro (b) apola (d) silebu
- ………..ni a n lo fun idagbasoke ilu. (a) iro (b) egbe (d) aaro.
- …………ni maa n gbo ju ninu silebu. (a) odo silebu (b) ihun silebu (d) apaala silebu.
- …… ki i se ara erongba elegbejegbe. (a) ona yiye (b) afara tite (d) aibowofagba.
- Apeere elegbejegbe laye atijo ni ………. (a) egbe onimototo (b) egbe ogboni (d) Rotary.
THEORY
- ki ni silebu?
- salaye ihun silebu pelu apeere.
- a. kin ni odo ati apaala silebu? Fi idahun re han pelu apeere.
- kin ni elegbejegbe?
- salaye iwulo elegbejegbe merin ti o mo.
See also
AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN
AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE