Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba.
Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni
- Ifesona (courtship)
- Ifayaran (perseverance)
- Suuru (patience)
- Ipamora (tolerance)
- Igbora-eni-ye (understanding)
- Ife aisetan (unconditional love)
IGBESE IGBEYAWO
- Ifojusode
- Iwaadi
- Alarina
- Isihun / ijohen
- Itoro
- Baba gbo, iya gbo
- Idana
- Ipalemo
- Ifa iyawo
- Ojo igbeyawo
- Ese iyawo wiwe
- Ibale
- Ikorun
- Ojo keje
Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun jijade eemi ni kaa enu nigba ti a ba n pe won. Ona meta ni a le gba mo iru iro konsonanti ti an pe. Awon ona wonyii ni:
- Ibi isenupe
- Ona isenupe
- Abuda iro konsonanti
- IBI ISENUPE: orisii mejo ni ibi isenupe iro konsonati ede Yoruba. Awon ibi isenupe wonyi bere lati ete lo si ibi otooto orule enu titi lo dopin. Awon naa ni:
(i) Afetepe
(ii) Afeyinfetepe
(iii) Aferigipe
(iv) Afajaferigipe
(v) Afajape
(vi) Afafasepe
(vii) Afafase fetepe
(viii) Afi-tan-an-na-pe
- ONA ISENUPE: orisii meje ni awon ana isenupe iro konsonanti awon ni won wa lori bi afefe eemi ti maa n jade nigba ti a ba n pe iro tabi soro. Awon ni:
- Asenupe
- Afunnupe
iii. Asesi
- Aranmupe
- Arehon
- Afegbe enupe
vii. Aseesetan
- ABUDA IRO KONSINANTI: ti a ba fe se apejuwe iro konsonanti ni ilana abuda, a ni lati wa awon ilana yii:
- Orisun eemi (eemi amisinu tabi eemi amisode)
- Ipo ti alafo tan-an-na wa (ipo imi tabi ipo ikun)
iii. Ipo afase (boya afase wa sile tabi o gbera soke)
- Irufe afipe ti a lo (yala afipe asunsi tabi akanmole)
- Irufe idiwo ti o wa fun eemi (boya ona se patapata tabi o si sile die)
See also
AKORI EKO: EYAN
AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)
AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN
OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI
ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA