Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012
Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT)
Ona ti a le gba dena ogun
- Ki ife ti o gbona wa laarin awon ara ilu
- Ki asoye tabi agboye naa wa laarin ara ilu
- Ni gba tie de ayede ba be sile eemi suuru se koko
- Nini emi idariji
- Ibowo fun omolakeji eni
- Iwa pele abbl.
Aleebu Ogun Jija
- Ogun maa n da ote si le laarin ilu meji
- Ogun a poju maa n fa iyan
- O maa n pa ilu run
- Gbogbo ohu amayederun ilu yoo denu kole
- O maa n fa airisese
- Ipadanu emi ati dukia maa n po ni akoko ogun abbl.
Anfaani Ogun Jija
- Ogun jija je ona ti a fi n da abo bo ilu lowo ote
- O n mu ki ilu wa ni imura sile ni gbogbo igba
- Ogun jija n mu ni mo o le ati alagbara ilu
- O n je ki a mo bi ilu eni se ni agbara ogun jija si.
Igbelewon :-
- Ko orisi ona marun-un ti a le gba dena ogun
- Ko aleebu ogun jija merin-in
- Anfaani wo ni ogun jija n se fun ilu
Ise Asetilewa :- Gbiyanju gege bi akekoo ede Yoruba lati gba aare orile-ede yii ni iyanju lori ona ti o le gba segun ogun agbesumobi (boko haram) ti o n yo orile ede wa yii lenu lati ojo to ti pe
LITERSO:- Kika iwe apileko ere onise ti ijoba yan.
See also
Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)
OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)
OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)
AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE
Eto ise fun saa keji