Akole ise: Itesiwaju lori eko iro ede Yoruba.
Iro ede ni ege ti o kere julo ninu oro eyi ti a le gboninu ede.
Orisi iro meta ti o se Pataki ninu ede Yoruba ni,
- iro faweli
- iro ohun
Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eeni ti a fig be won jade apepo iro konsonanti ede Yoruba je meji dinlogun (18). B d f g gb h j k l m n p r s s t w y.
Idako konsonanti ni liana international phonetic association (IPA)
B /b/
D /d/
F /f/
G /g/
Gb /gb/
H /h/
J /d3/
K /k/
L /l/
M /m/
N /n/
P /kp/
R /r/
S /s/
S /s/
T /t/
W /w/
Y /j/
Iro faweli ni iro ti a pe laisi idiwo kan kan fun eeni.
A le pin iro faweli si ona meji
- Iro faweli airamupe – a e e I o o u
- Iro faweli aranmupe – an en in on un
Apapo iro faweli Yoruba je mejia (12)
Adako iro faweli ni ilana IPA.
A /an/
E /e/
I /i/
O /o/
O />/
U /u/
An /a/
En /£/
In /i/
On />/
Un /u/
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: ISE ABINIBI
Ise abinibi je ise iran ti a jogun lati owo awon baba nla wa.
Yoruba gbagbp pe “ise loogun ise”, won lodi si iwa imele idi niyi ti o fi je pe iran kookan ni o ni ise abinibi ti won n se.
Lara ise abinibi ile Yoruba ni wonyi;
- Ise agbe
- Ise ode
- Ise owo bii,
- Aso hihu
- Eni hihu
- Ilu lilu
- Ise isegun
- Ise agbede
- Ise gbenagbena
- Epo fifo
- Ikoko mimo
- Igba finfin
- Irun didi
EKA ISE: LITIRESO
AKOLE ISE: EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN
Orisirisi igbadun ni onworan ati onkowe maa n je ninu litireso alohun.
lara awon igbadun naa ni wonyi;
- Isowo-lo-ona ede: Ilo ede Yoruba je ijinle aladun litireso. Elo ede ti a maa n ba pade ninu litireso alohun ni wonyi; owe, akanlo-ede, ewi tunwi, afiwe taara, afiwe ela loo, iforodara, asorege, oro apara, abbl.
Awon ona ede yii kii je ki litireso atenudanu su eniyan, o si maa n mu ki awon eniya gbadu re to bee gee de ibi wi pe won kii fe ki o tan.
Awon oluworan yoo maa ho yee, won yoo si ma patewo nitori pe o n mu ki inu won dun.
- Ilo ohun didun: ohun didun ninu ewi kika, orin kiko, alo pipa ati itan siso ko gbeyi ebun ni ohun, olodumare si fun wa ni esun yii ju ara wa lo de bi pe ti elomiran ba n ke ewi tabi ko orin bi eni pe ki o maa dake mo ni.
- Ilu, orin ati ijo: Ni akoko odun ibile bii, odun egungun, odun ifa, odun oro, odun ogun, odun sango odun obatala,lasiko ayeye bii, oye jije, isile, igbeyawo, isomoloruko, isinku agba abbl ni a maa n ko okoojokan orin oladun ati onirunru ilu ni a n li si orin yii ti a si n jo si.
Igbelewon:
- Fun iro ede loriki
- Salaye orisi iro ede ti o wa ninu ede Yoruba
- Kin ni ise abinibi?
- Daruko oniruuru ise abinibi ile Yoruba
- Ko igbadun ti o wa ninu litireso alohun
Ise asetilewa: ya ate faweli aranmupe ati airanmupe sori kadiboodu feregede
See also