Ere – onise – ese/iwi egungun , ijala
- Oriki itan isedele tabi eyi to n so idi abajo litireso atenudenu Yoruba ni eyi, awon ohun ti o n suyo nibe ni oriki itan isedale ati awon asa ajogunba Yoruba.
- Kiki ati kike je okan lara igbadun litireso atenudenu. Awon itan isedala ti a maa n ba pade ninu litireso atenudenu maa ran ni leti orirun ibi ti awon eniyan kan ti se, ti o si n je ki a ni ife sii daadaa.
- Ba kan naa, awon itan idi abajo , bi ori igun se pa, idi ti oju orun fi jinna si ile , idi ti a fi n bo oku mole abbl ni a maa n ba pade ninu litireso atenudenu.
- Eko ati ogbon: onirunru eko ni a maa n ba pade ninu litireso atenudenu , o maa n fi oye awon ohun ti o ye ki a maa se ati eyi ti ko ye ki a hu niwa han ni.
- Ikorajopo, idaraya, ipanilerin ati tita-opolo ji po jatirere ninu litireso atenudenu lati gbe asa Yoruba laruge.
Igbelewon:
- Sapejuwe iro faweeli ni ona merin
- Fun owe ni oriki
- Salaye orisi owe pelu apeere
- Ko igbadun ti o wa ninu litireso alohun ere onise
Ise asetilewa: 1. salaye awon owe wonyi gege bi o ti ye o si pelu apeere irufe owe bee meji meji
- owe imoran
- Owe ibawi
- Owe ikilo
See also
ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA