JSS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)

AKOLE ISE:-  Ede:-  Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori oro Aroso Asotan Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo Ayeye ere onilejile ti o koja ni ile-iwe mi Isomoloruko omo egbon mi obinrin.   […]

OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY) Read More »

Onka Yoruba (101 – 300)

Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA 101 OOkanlelogorun-un 102 Eejilelogorun-un 103 Eetalelogorun-un 104 Eerinlelogorun-un 105 Aarundulaa-adofa 106 Eerindinlaa-adofa 107 Eetadinlaa-adofa 108 Eejidinlaa-adofa

Onka Yoruba (101 – 300) Read More »

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi

Salako:-         Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:-        Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:-                       Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :-        Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o Adunmi :-      Bi o se emi ati ile mi, buburu kan

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi Read More »

EYA GBOLOHUN

Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re.   Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko   Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka “ti” tabi “bi”. Apeere. Awon ole yoo sa bi

EYA GBOLOHUN Read More »

Eto ise fun saa keji

Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye)   Ose keji: Ede aroso alapejuwe Asa-asa iranra-ero lowo Litireso-ewi alohun to je mo esin ibile – ijala – iremoje – iyere ifa – ese/iwi – egungun   Ose

Eto ise fun saa keji Read More »

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA Eni hihun Ikoko mimu Irin riro Aro dida Igba finfin abbl. Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba.   ISE IKOKO MIMO: ise ikoko mimo wopo ni agbegbe Ilorin, oyo, ipetunmodun, ise obinrin ni ise ikoko mimo, awon ohun elo ikoko mimo ni wonyi; Amo, omi, odo, isaasun obe,

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA Read More »

Ede:- Akaye oloro geere

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:-  Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba ni lasiko. Ipa Ti Asa Iranra-Eni Lowo N Ko Ninu Ise Ajumose At

Ede:- Akaye oloro geere Read More »

YOU HAVE 1 NEW MESSAGE

$50,000 worth of Scholarships & Free Visa

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad
Acadlly