Onka Yoruba (101 – 300)

Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun.

Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba.

Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta

ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA
101 OOkanlelogorun-un
102 Eejilelogorun-un
103 Eetalelogorun-un
104 Eerinlelogorun-un
105 Aarundulaa-adofa
106 Eerindinlaa-adofa
107 Eetadinlaa-adofa
108 Eejidinlaa-adofa
109 Ookandinlaa – adofa
110 Aadofa
111` Ookanlelaa-adofa
112 Eejilelaa-adofa
113 Eetalelaa-adofa
114 Eerinlelaa-adofa
115 Aarundinlogofa
116 Eerindinlogofa
117 Eetedinlogofa
118 Eejidinlogofa
119 Ookandinlogofa
120 Ogofa
121 Ookanlelogofa
122 Eejilelogofa
123 Eetalelogofa
124 Eerunlelogofa
125 Aarundinlaa-adoje
126 Eerundunlaa-adoje
127 Eetadunlaa-adoje
128 Eejidunlaa-adoje
129 Oookadinlaa- adooje
130 Aadoje
131 Ookanlelaa –adoje
132 Eejilelaa-adoje
133 Eetalelaa-adoje
134 Eerunlelaa-adoje
135 Aarundinlo-goje
136 Eerundinlogoje
137 Eetadiinlogoje
138 Eejidinlogoje
140 Ogoje
141 Okandinlogoje
142 Eejilelogoje
143 Eetalegoje
144 Eerunlelogoje
145 Aarundunlaa-adoje
146 Eerundinlaa-adoje
147 Eetadinlaa-adoje
148 Eejidinlaa-adoje
149 Ookandinlaa-adoje
150 Aadojo
151 Ookanlelaa-adojo
152 Eejilelaa-adojo `
153 Eetalelaa-adojo
154 Eerunlelaa-adojo
155 Aarundinlogojo
156 Eerundinlogojo
157 Eetadinlogojo
158 Eejidinlogojo
159 Ookandinlogojo
160 Ogojo
161 Ookanlelogojo
162 Eejilelogojo
163 Eetalelogojo
164 Eerunlelogojo
165 Aarundinlaa-adosan-an
166 Eerundinlaa-adosan-an
167 Eetadinlaa-adosan-an
168 Eejidinlaa-adosan-an
169 Ookandinlaa-adosan-an
170 Aadosan-an
171 Ookanlelaa-adosan-an
172 Eejilelaa-adosan-an
173 Eetalelaa-adosan-an
174 Eerunlelaa-adosan-an
175 Aarundinlogosan-an
176 Eerundinlogosan-an
177 Eetadinlogosan –an
178 Eejidinlogosan-an
179 Ookandinlogosan-an
180 Ogosan-an
181 Ookanlelogosan-an
181 Ooknlelogosan-an
182 Eejilelogosan-an
183 Eetalelogan-an
184 Eerunlelogosan-an
185 Aarundinlaa-adowaa
186 Eerundunlaa-adowaa
187 Eetadinlaa-adowaa
188 Eejidinlaa-adowaa
189 Ookandinlaa-adowaa
190 Aadowa/igba-o-din kewa
191 Ookanlelaa –adowa
192 Eejilelaaa-adowa
193 Eetalelaa-adowa
194 Eerunlelaa-adowa
195 Aarundiin-nigba
196 Eerundin-nigba
197 Eetadin-nigba
198 Eejidin-nigba
199 Ookandin-nigba
200 Igba/ogowaa
201 Igba ole-kan
202 Igba ole-meji
203 Igba ole-meta
204 Igba ole-merin
205 Igba ole marun-un
206 Igba ole-mefa
207 Igba ole-meje
208 Igba ole-mejo
209 Igba ole-mesan-an
210 Igba ole-mewaa
211 Ookoolenigba-odun mesan (220-9)
212 Okoolenigba-odun mejo (220-8)
213 Okoolenigba-odun meje (220-7)
214 Okoolenigba-odun mefa (220-6)
215 Okoolenigba-odun marun-un (220-5)
216 Okoolenigba-odun merun (220-4)
217 Okoolenigba –odun meta (220-3)
218 Okoolenigba- odun meji (220-2)
219 Okoolenigba-odin kan (220-1)
220 Okoolenigba
221 Okoolenigba ole-kan
222 Okoolenigba ole-meji
223 Okoolenigba ole-meta
224 Okoolenigba ole- merin
225 Okoolenigba ole-marun-un
226 Okoolenigba ole-mefa
227 Okoolenigba ole-meje
228 Okoolenigba ole-mejo
229 Okoolenigba ole-mesan-an
230 Okoolenigba ole-mewaa/ojilenigba odin mewaa
231 Ojinlenigba odin-mesan-an
232 Ijilenigba odin-mejo
233 Ojilenigba odin-meje
234 Ojilenigba odin- mefa
235 Ojilenigba odin -marun-un
236 Ojilenigba odin-merin
237 Ojilenigba odin-meta
238 Ojilenigba odin-meji
239 Ojilenigba odin-kan
240 Ojilenigba
241 Ojilenigba ole-kan
242 Ojilenigba ole-meji
243 Ojilenigba ole-meta
244 Ojilenigba ole-merin
245 Ojilenigba ole-marun-un
246 Ojilenigba ole-mefa
247  Ojilenigba ole-meje
248  Ojilenigba ole-mejo
249 Ojilenigba ole-mesan-an
250 Ojilenigba odin-mesan-an
252 Otalenigba odin-mejo
253 Otalenigba odin- meje
254 Otalenigba odin-mefa
255 Otalenigba odin-marun-un
256 Otalenigba odin-merin
257  Otalenigba odin- meta
258 Otalenigba odin-meji
259 Otalenigba odin-kan
260 Otalenigba
261 Otalenigba ole-kan
262 Otalenigba ole-meji
263 Otalenigba ole-meta
264 Otalenigba ole-merin
265 Otalenigba ole-marun-un
266 Otalenigba ole-mefa
267 Otalenigba ole-meje
268 Otalenigba ole-mejo
269  Otalenigba ole-mesan-an
270  Otalenigba ole-mewa/orulenigba odin-mewaa
271 Orinlenigba odin-mesan-an
272 Orinlenigba odin-mejo
273 Orinlenigba odin-meje
274 Orinlenigba odin mefa
275 Orinlenigba odin-marun-un
276 Orinlenigba odin-merin
277 Orinlenigba odin-meta
278 Orinlenigba odin-meji
279 Orinlenigba odin-kan
280 Orinlenigba
281 Orinlenigba ole-kan
282 Orinlenigba ole-meji
283 Orinlenigba ole-meta
284 Orinlenigba ole-merin
285 Orinlenigba ole-marun-un
286 Orinlenigba ole-mefa
287 Orinlenigba ole-meje
288 Orinlenigba ole-mejo
289 Orinlenigba ole-mesan-an (280+10)
290 Orinlelugba ole-mewaa/odunrin odin-mewaa (300-10)
291 Odunrun odin mesan-an (300-9)
292 Odunrin odin mejo (300-8)
293 Odunrin odin meje 300-7)
294 Odunrin odin mefa (300-6)
295 Odunrun odin marun-un (300-5)
296 Odunrun odin merin (300-4)
297 Odunrun odin meta (300-3)
298 Odunrun odin meji (300-2)
299 Odunrun odin kan (300-1)
300 Oodunrun

 

Eka ise:- Asa

Akole ise: ise akanse kan ni Awujo  Yoruba (project)

Gege bi a se salaye ninu idanilekoo ti o koja pe oniruru ise isenbaye/abinibi ni a n se ni ile Yoruba.

Lara ise akanse ile awujo Yoruba ti a oo da wole ni sise ni ose yii ni ;

  1. Aro dida
  2. Ikoko mimo

 

Eka ise:- litreso

Akole ise:- litreso alohun to je mo ayeye /kika iwe apileko ti ijoba fowo si.

Lara litreso alohun ti o je  mo ayeye ni,

  1. Rara
  2. Bolojo
  • Alamo

 

Rara

Rara je litreso atigbadegba lawujo Yoruba. A n lo o lati fi oba, ijoye, olowo, olola, gbajum han .

Awon obinrin ile to  mo atupale oriki oko daadaa maa n fi rara sisun pon oko le. Tokunrin tobinrin ni o n sun rara.  Ewi yii wopo ni agbegbe Iseyin, Ogbomoso, Ede, Ikirun, Ibadan.  Apeere,

Akanni o

Omo lofamojo

Omo ola lomi

Kekere olowo oko mi o

T ‘ori’ lukuluku

B ‘emo eebo

Bolojo

A n ko orin bolojo lati fi se  aponle, tu asiri, se efe, soro nipa oro ilu, oro aje, ki eniyan to n se rere ati lati dekun iwa aito.

Awon okunrin yewa ni o saba maa n ko orin bolojo. A n ko orin bolojo ni ibi ayeye igbeyawo isomoloruko, oye jije, isile abbl. Apeere

Bo sale e wa ba mi lale

Bo si je koro wa ba mi o jare

Bo sale e wa ba mi lale

Ohun o ba fi mi se

Gbogbo aye ni n o ro o fun

 

Alamo

Won n salamo lati bu eniyan ti n huwa ibaje bee ni won n loo lati ki eni to ba n nawo fun won ni bi ayeye.

Ewi yii gbajumo laarin awon ekiti. Awon obinrin ni o maa n salamo pelu eka ede ekiti.

Igbelewon :

  • Kin ni onka?
  • Ka onka lati 101-300
  • Mu ise akanse kan ni awujo ki o si salaye lekun un rere
  • Daruko awon litireso alohun ajemayeye ki o si salaye

Ise asetilewa: mu okan lara ise akanse ile Yoruba wonyi ki o fi se ise se:

  1. Ikoko mimo
  2. Eni hihun

 

See also

LITIRESO ALOHUN TO JE MO AYEYE

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA

Kika Iwe Apileko Oloro Geere Ti Ijoba Yan

EYA GBOLOHUN

AKOLE ISE

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *