Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe
- Ile iwe mi
- Ilu mi
- Oja ilu mi
- Ounje ti mo feran
- Ile isin wa
- Ijanba oko kan ti o sele loju mi abbl.
Ilana to se Pataki fun aroko asapejuwe
- Yiyan ori oro
- Sise arojinle ero lai fi kan bokan ninu
- Sise apejuwe oro la see se sinu iwe ni ipin afo (paragraph) kookna.
Igbelewon :–
- Kin ni aroko
- Fun aroko asepejuwe ni oriki
- Ko ori ora aroko asapejuwe marun-un
Ise asetilewa:-yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe ketadinlogbon Eko kerinla
ASA:- Asa Iran-ra-eni lowo ni ile Yoruba
Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba e ni asiko pipe.
Ona iranra-eni lowo ni aye atijo eti ni ode oni ni wonyi :-
- Esusu
- Ajo
- Awe
- Aaro
- Arokodoko
- Egbe alafowosowopo
Igbelewon :–
- Salaye asa irara-eni lowo
- So iyato to wa laarin awon wonyi
- Esusu ati ajo
- Owe ati aaro
Ise asetilewa:- yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe kokandinlogbon Eko kerindinlogun
LITIRESO:- IWE KIKA – ERE ONISE
See also
AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE
Eto ise fun saa keji
ASA IGBEYAWO
AKORI EKO: EYAN
AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)