SS 1 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko atonisona asotan Aroko oniroyin Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko Yiyan ori-oro: A […]

AKOLE ISE: AROKO KIKO Read More »

AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.     Apeere apa silebu ni wonyi; APA ALEYE APEERE ORO APA (a)    Odo

AKOLE ISE: SILEBU Read More »

EKA ISE: EDE

Akole ise: Itesiwaju lori eko iro ede Yoruba. Iro ede ni ege ti o kere julo ninu oro eyi ti a le gboninu ede. Orisi iro meta ti o se Pataki ninu ede Yoruba ni, a.iro konsonanti iro faweli iro ohun Iro konsonanti ni iro ti idiwo maa n wa fun eeni ti a fig

EKA ISE: EDE Read More »

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e

EKA ISE: EDE Read More »