AKOLE ISE: SILEBU
Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu. Apeere apa silebu ni wonyi; APA ALEYE APEERE ORO APA (a) Odo […]