YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK
YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK, Get the latest Scheme of work for your studies, Nigerian Scheme of work for Senior Schools,
Scheme of Work for Nigeria Curriculum,
YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK Read More »
YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK, Get the latest Scheme of work for your studies, Nigerian Scheme of work for Senior Schools,
Scheme of Work for Nigeria Curriculum,
YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK Read More »
Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon. EYA ARA IFO EYA ARA IFO
Iro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti
Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, s, t, w, y. APEJUWE IRO KONSONANTI AKOONU Iro Konsonanti: ni iro
Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa
Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si. Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun, orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa ipin keji ni awon eniyan ti a so di orisa nitori ise ribiribi owo won
AWON ORISA ILE YORUBA Read More »
Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n
AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe. A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo + kobo = kobokobo Odun + odun = odoodun Ale + ale = alaale Osu + osu = osoosu Osan + osan = osoosan Egbe
ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE Read More »
AKOLE ISE:- Ede:- Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori oro Aroso Asotan Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo Ayeye ere onilejile ti o koja ni ile-iwe mi Isomoloruko omo egbon mi obinrin.
OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY) Read More »
Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.
AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Fun Apeere Wa-je oro onisilebu kan nitori pe ami ohun kan ni o wa lori re. I / we = 2 Ba /
ORI-ORO | SILEBU EDE YORUBA Read More »
Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Ise ti mo fe lojo iwaju. Ki
AROKO AJEMO ISIPAYA Read More »
Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun onibo/olo po oro-ise Gbolohun Abode/Ele yo oro-ise Gbolohun Abode je gbolohun ti kii gun Gbolohun Abode kii ni ju oro-ise eyokan lo. Apeere, Bata re
Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence) Read More »
Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu (a) Oro apejuwe le yan oro – oruko ni ipo oluwa. Apeere; – Oruko rere san ju wura oun fadaka lo – Iwa bukuku ko
Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun Read More »
Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. Ise Oro-Oruko Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun – Oluwa ni oluse nnkan ninu gbolohun apeere; Ayinde ra aso Ojo je ewa Oro oruko maa n wa ni ipo abo ninu gbolohun – Eyi
ISE ORO ORUKO ATI ORO AROPO ORUKO NINU GBOLOHUN Read More »
Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re. Aroko oniroyin je aroko ti o jo mo iroyin sise. Eyi le je kiko sile tabi si so lenu. Awon Igbese/Ilara Kiko Aroko Oniroyin Mi mu ori-oro ti a fe ko nnkan le Ki ko koko ohun ti a fe
AKOLE ISE- EDE: AROKO ATONISONA ONIROYIN (NARRATIVE ESSAY) Read More »
Ni aye ode-oni eto iselu ti yato patapata is ti aye atijo. Ni aye ode-oni, eto iselu ti aye ode-oni ni a n lo gomina ni Olori ati alase ni ilu kookan ti o si ni awon komisanna ti won jo n tuko eto ilu. Loooto ni awon oba si wa sugbon won ko ni
Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara
AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO Read More »
Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA 101 OOkanlelogorun-un 102 Eejilelogorun-un 103 Eetalelogorun-un 104 Eerinlelogorun-un 105 Aarundulaa-adofa 106 Eerindinlaa-adofa 107 Eetadinlaa-adofa 108 Eejidinlaa-adofa
Onka Yoruba (101 – 300) Read More »
Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :- Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o Adunmi :- Bi o se emi ati ile mi, buburu kan
Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi Read More »