Yoruba

ASA IGBEYAWO

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional love)   IGBESE IGBEYAWO Ifojusode Iwaadi Alarina Isihun / ijohen Itoro Baba gbo, iya gbo

ASA IGBEYAWO Read More »

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko –

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA Read More »