Yoruba

EYA GBOLOHUN

Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re.   Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko   Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka “ti” tabi “bi”. Apeere. Awon ole yoo sa bi […]

EYA GBOLOHUN Read More »

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ASEYE

Litrreso alohun ni litireso ti a fi ohun enu gbe jade ti a jogun lati odo awon babanla wa. Apeere litireso alohun ajemayeye ni i               Ekun Iyawo ii              rara ii              Bolojo iv             Apepe v              Dadakuada abbl   Ekun iyawo gege bi litireso alohun ayeye Ekun Iyawo je ewi ti omo binrin ti n lo

AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ASEYE Read More »

AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro  kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I               faweli nikan –(F) ii              Apapo konsonati ati  faweli (KF) iii             Konsonati aranmupe asesilebu (N)

AKOLE ISE: SILEBU Read More »

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

IGBESE LETA AIGBEFE Adiresi: Adiresi akoleta (The writer’s address) Adiresi agbaleta (Receiver’s address) Deeti (the day’s date) iii. Ikini ibeere (salutation) Akole leta (the tittle / heading) Koko leta (main content) Ikadii / ipari leta (conclusion)   Leta aigbagbefe / aigbefe (Formal letter) Eyi ni leta ti a maa n ko si awon eniyan ti

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER) Read More »